Haaa haaa 😅😅😅😅 kilode Eyin ijoba 9ja esi beru olohun esi beru atunbotan ojo atisun 😂😂😂😂 Eyin nu olohun nu ooo
@akandeolusesan98515 күн бұрын
Gbogbo eyin ota orile ede Nigeria ati eyin ota mekunnun ibinu Olorun maba gbogboyin ati iran de iran yin ni odun yi 😢
@rossyrossy51105 күн бұрын
Let Dangote too take it essy ...Must he make the money he invested in just within a year ...how can he be planing to refine more expensive than imported ones ...We are not blind we know how it's going ...
@OlasunkanmiFasasi5 күн бұрын
Won fe ba ti ara won je Ko si afenifere ni orilede yi Ilu afenifebi ni won.
@IlalaMoney5 күн бұрын
My president asiwaju you can sort this matter please for god sake ❤❤❤
@imamabdulrasaq4015 күн бұрын
Hmmmm Nigeria Tinubu Eyin nu olohun nuu
@LukmanAgbaje5 күн бұрын
Hmmmmm Nigeria 🤔🤔🤔🤔
@fatalkehinderaheemat15135 күн бұрын
Ti awon nnpc ti won ba ti lo si orun ki won gbe gbogbo Nigeria dani nitori gbogbo re ko lo titi ki won jara mo
@omoshewayinka25815 күн бұрын
Ju gbogbo ę lo , Olorun a yo wa a dę kowa yò... we shall survive it by God’s grace.
@NurudeenAkeem-r8e4 күн бұрын
Lagbara olohun alanun julo Olohun yio mun gbogbo won sodo laipe o, lagbara olohun alanun julo gbogbo eni to da Nigeria lamun simin ti ran diran o AMIN NAA yalahu
@aladjimoustaphaiguewassiou95762 сағат бұрын
Oloriburuku ni gbogbo wọn,
@marufolakunle75695 күн бұрын
Who dangote help in Nigeria, bird with same feather
@sakenatafolabi86665 күн бұрын
NIGERIA HMMMMMMMMM 🤔
@wosilatamosu90174 күн бұрын
Dangote OWO tani onna ?sebi Owo Omô NIGERIA ni oyaa tikosi sans pada OLE gbe OLÉ gba Obasanjo Tania Ni AJALA Olorun nbe Yoruba Nation No going Back Réveille SOLUTION Niyen Huuuum GOD Blessed YORUBA LANDS First 🙏🏿
@aladjimoustaphaiguewassiou95762 сағат бұрын
Tinubu náa sowo epo, oloriburuku
@saheedadewale59014 күн бұрын
Se won kin se eniyan nii
@taiwoolusholaajokeaade33343 күн бұрын
E beru olorun oooo
@taiwoolusholaajokeaade33343 күн бұрын
Hmmmmmmm Najiriyaaaa Olorun a ko wa yo nbe
@helenadegoke69224 күн бұрын
What goes around comes around, there's consequences for every act of greedness
@saheedadewale59014 күн бұрын
Awon tani NNPC gan
@aladjimoustaphaiguewassiou95762 сағат бұрын
Tinubu gán gán ni ìṣòro Naijiria , o ṣẹṣẹ bẹrẹ Si hàn sí gbogbo ayé ni ,
@ElishaOlasomi-fx3wx4 күн бұрын
Ayafi ti won ba deal pelu awon cabal ni ile ise elepo, Nigeria ko le roju.
@adewaleadeniran25343 күн бұрын
Alaroye asodun yin ti poju se dangote nikan lo ni Ile aiye nii die pelu itelorun ere nla nii
@CHAMPIONOILANDGAS5 күн бұрын
Nigeria 🇳🇬 🇳🇬 my country🤔🤔🤔🤔🤔
@muhideenakorede29943 күн бұрын
2500per liter is not bad❤
@kosemanitaofeek53935 күн бұрын
1,450 per liter, in River's State
@SamuelAjasin4 күн бұрын
Same here in osun state
@OmidijiOdunayo5 күн бұрын
Ole Gbe, Ole Gba Ni Oro Awon Opolopo Olowo Nigeria.....Sebi Lamidi Ni NNPCL.... OJU OLUWA N'WO GBOGBO WON.... Ki Dangote Lo Fi Okan Bale.. Tinubu Ni Are Lowolowo..