Kádé pẹ́ lórí Kabiyesi ooo, Ẹ kú isẹ ooo aya Olatunji
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@gbadegesinaasa8455 Жыл бұрын
Kabiyesi, Oba Inisa, Olorun yio fun yin ni emi gigun ati alafia pipe.
@isedaleabinibiwa2020 Жыл бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè àti ẹ̀yin náà o
@saheednihmatolawumi89352 жыл бұрын
Wow💕💕🙈💕💕💕💕
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Ẹ ṣeun púpò o
@shola81952 жыл бұрын
Good one. Well done orente
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@adejumogabriel31302 жыл бұрын
Kabiyesi o. Bi ale yoo seri ebi owuro lere. Ojo adale o amin
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun o
@shola81952 жыл бұрын
Well done orente
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Ẹ ṣeun o
@ajayiolatunji35112 жыл бұрын
Lovely!
@isedaleabinibiwa20202 жыл бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀
@gbadegesinaasa8455 Жыл бұрын
Lati gbe asa Yoruba l'aruge, mo l'ero wipe o to, o si ye ki atokun eto mura gege bi Omo Yoruba tooto paapaa nigbati won ba wa ni aafin àwọn Oba ni afin. Nitori naa, mo fe gba momo wa Adeola Olatunji nimoran la ti ma we gele pelu aso iro won. Oduduwa yio gbe wa o.