Apá kewa yí ni alaye lori bí lára àwọn jagunjagun Ibadan ṣe lọ tẹ Abeokuta àti igbehin ayé Mayẹ OKunade. Laji Abbas Whatsapp Telegram +
Пікірлер: 4
@hamzatjamiu49263 жыл бұрын
May Almighty Allah bless you and your generation
@wosilatamosu90174 жыл бұрын
HUUUUM OLORUN Ashanu wa gbenigbeni leni lati aye Awon Baba lotibere Tobe jubelo Omo Yoruba Ejigiri kaparapo lati gba arawa kale ASE Laji Abbas Eshun pupo pupo Yoruba EMA RONU MO Ejigiri kiakia
@akeemadedayo96264 жыл бұрын
Olurun oni paa lakaiye yin Oluko Agba.
@olumakinwaisingbadebo7063 жыл бұрын
Ojogbon ninu itan Yoruba lo d'ara fun yin bayi, Oluko agba