Rara o Oro eleyi o ri bee o. Idi ni pe,awon elegbe yii ni won ma n dipanpa lo KO igba awon ti won BA dinwo oja tiwon Ku diedie. Fun idi eyii mo fi ara mo ohun ti kabiyesi se ni ida adorin
@okeperfecta2313 ай бұрын
Baba oloye nla you are really qualified to be onibode of yoruba land gbefun baba the courage is unparalleled respect respect respect and multiple respect for you history will not forget you
@kehindejosephkashimawo94103 ай бұрын
Ẹ ṣeun.. Mo gbádùn rẹ̀... Gbé fún!!! Ọ dá alábọ̀dè Àdégún Oníkòyí lara .. Nai!!! Bí yóò ṣe rí fún àwọn olóṣèlú, Ọba, Ìjoye, Baalẹ̀,, Gomina. M, Ọ̀tọ̀kùlú ati gbogbo awọn tó ń gbàbọ̀dè fún wa nílẹ̀ Yoòbá nùu.. Lori ọ̀rọ̀ Ọ̀ọ̀ni to ni àwọn má tú àwọn egbe oloja ká tí àwọn kan ngbe lórí agbagbe. Mo wí fún wọn pé Ọ̀ọ̀ni kò lagbára láti gbé irú ìgbésẹ̀ bẹ́ẹ̀ lábẹ́ òfin ilẹ̀ Nigeria.. Láti ojo ti Fulani tí nfi ẹran jẹ oko ńjẹ bàbá wa Ọ̀nirìṣà fìgbà kan gbé ìgbésẹ̀ tàbí sọ̀rọ̀ akin lórí èyí..? Pelu awon ti wọ́n ń wa kùsà ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tí wọ́n jẹ́ olorí igbimo lọbalọba.. Àwọn tí wọ́n bá nta ọjà na gbodo sowo jẹ èrè Now? Àbi báwo ni bàbá wa Ọ̀ni àti àwọn yókù ṣe ní èrò pé kí àwọn iyalọjà àti bàbálọja ra ọjà ọ̀wọ́n kí wọ́n wà tá lọ̀pọ̀..?? Oun tó yẹ ki bàbá wa mojuto wọn ò mojuto.. Ayafi ki wọn maa yọ fòròfòrò káàkiri.. Wọ́n tún ti gba Ṣọ́ọ̀ṣì ìyá Esther lọ láìpẹ́ yìí.. Àwọn yí kan na ni wọ́n ń sáré jànà-jànà lọ bá Buhari ni Abuja to ń rán wọn níṣẹ́ sì Olóyè Sunday Ìgbòho pé kò dákẹ́ lori ọ̀rọ̀ Yorùbá.. Ti àwọn náà sì ń wá jẹ́ irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ fún wa..? Ọ́ ti ní lójú púpọ̀.. Wọ́n wá sọ ipò Arólé Oodua di yẹ̀yẹ́..
@Adekola-gu1fl3 ай бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤Aare, Ki E Pe Ooo
@AdesolaOladeji-d8m3 ай бұрын
Aare lahji abass kemi yin ogun ewo lewo ninu won ati tinubu ati awon agbagba yoruba unkan kanhun
@gbengaolaitan3533 ай бұрын
We will go any length because of that phone
@adewumimonsuru40523 ай бұрын
Bámi òkè lọwọ afunní ngbé òke òkè lẹ oo má rè.👁️
@banirefatiualao92493 ай бұрын
Wallahi,awon baba wa ti se were gan o. Olohun darijimi
@banirefatiualao92493 ай бұрын
@@LewisMuturi-b7u rara o, a o tun gbodo fi gbogbo enu bu tabi soro odi si won na oo. Lotito, ohun ti won SE buru jai sugbon,bi nkan SE ri nigba naa ni. Leyii ti i tumo sii pe o seese ki EMI ati eyin naa SE iru awon asise bayii ti a BA n be laiye nigba naa
@DutchmanPounds3 ай бұрын
LOL 😂😂😂😂😂 Nigeria 🇳🇬 my country
@AdesolaOladeji-d8m3 ай бұрын
Amin ase
@isaacisaacson94303 ай бұрын
eni gbadire otosi ogbe talaroye
@gbengaolaitan3533 ай бұрын
Nigeria custom dey play....they must release the phone
@loantha29963 ай бұрын
They're immature for iPhone
@imole-ayoonegod43063 ай бұрын
I lost 3 cellphone 📱📱📱 on their hands,custom and post offices are criminal organisations, Awon oole oloriburuku lon dari e
@ayinlamedia18323 ай бұрын
♥♥♥♥♥
@olupeters52013 ай бұрын
❤❤❤❤❤❤❤
@igebamidele40583 ай бұрын
You are just talking nonsense o bàbá oloye, no be history you dey tell us, you no even let get interest your story again nawa o