Abi o, let them arrest the person dat brought her to work.
@saheedadewale59012 ай бұрын
Osun osogbo
@classyjoyce54522 ай бұрын
This is serious ooo what is going on in this country Nigeria very bad God please save those children
@AdekunleZainab-yt7tk2 ай бұрын
Imu nika ko jeki a gborun asebi😱
@LukmanAgbaje2 ай бұрын
Hmmmmm iru ki leleyi
@christianahmodupeabiodun-o5972 ай бұрын
Eni to mu Omo yi wa lati kose da. Bawo lo se je si Oga ise yi. Eni to mu wa lati kose lo ye ki Olopa koko lo mu. Nibo lo ti moo ko to di pe o mu wa lati ko ise. Ko seese ki eniyan mu Eni ti ko mo ri wa lati ko ise. Afurasi ni Eni yi, boya ohun ati omo yi jo n sise laabi ni oo