Kí Olódùmarè ó jẹ́ kí wọn ó jáwọ́ nínú ìwà kébekèbe lórí afẹ́fẹ́ ayélujára pátápátá.. Àwọn adójútini gbogbo! Ìfẹ́ owó àfẹ́jù, àìlámòjúkúrò, olè, ọ̀lẹ, àìní ẹ̀kọ́ tó yanranhuntí àti àtẹnujẹ ti báwọn mulẹ̀ bíi ẹ̀gbẹ iṣu. Olódùmarè á ṣíwọn lójú inú láti rí ìjàmbá ńlá tí àwọn ǹkan wọ́nyí ń fà fún Ìṣẹ̀ṣe wa. Àṣẹ. Ride on Akifá.