Iba agba Asiri L'aye, e seun pupo-pupo. Ewe a maa je ooo!!! (1.) Se a le ra ikaraun igbin àkúsíjù yen ni odo awon l'eku-l'eja ti o ba je ojuda abi eyi ti a ba ri he ninu igbo tabi èbá-ònà ni a le lo ooo? (2.) Se normal ewe alupaida ni tabi ewe alupaida funfun? (3.) Se a ma ko oju igbin ti a ti we ni ikobere yen s'ókè ni abi a ma k'oju re s'ílè nii ti a ba ti fee rimo'le ni igun(corners) ibi ti a ti fee loo ni. Ewe a maa je ooo!!! Mo se'ba agba ooo!!!
@lawalismail92638 ай бұрын
Tobati dayinlonu wipe ojudani kosi waala esi ojú ikarahun igbín non soke