Baba onpitan ,I so much love you ,nitiripe Olorun fun yin ni ogbon ,oye ati imon ,eyinki Se adaluru ,atun ilu se ni eyin ,Mogbadura wipe eti goke eni jabo lailai,ese eku atunse
@RussiaPriceless5 ай бұрын
You're a TRUTH-SAYER! May the Almighty :God continue to bless your home, bless your programme and bless Ibadan Land bcos of you🙏 Continue your good-work The ALMIGHTY GOD is behind you..🤔
@everg45695 ай бұрын
Ole Oluwo alapa masise guy man, 419 , wokewoke
@oladiran47075 ай бұрын
Baba Laji Abass, e ku ise o. Olorun yoo ma wa pelu yin o. Amin.
@rachealolaifa5425 ай бұрын
Baba wa Opitan,Olorun yio ma wa pelu yin. Imam Ogbomosho Yi ti fi ara re han pe omo Ale lohun nitooto. Omode to ba Fe dagba ko ni yaju si Agbalagba, shee oye esin ju oye Oba lo ni? Imam Ogbomosho ati Imam Iwo ko ni pe subu lagbara Olorun ati awon onile.
@MikhailAwolowo-zm7fr5 ай бұрын
Dauda Omolasan, ti o ba da ogun esin sile, idi ogun ni won maa be ori e si. Iwo eranko to ngbe laarin eniyan yi.
@ditty68285 ай бұрын
@@LewisMuturi-b7u😂😂😂😂😂😂😂.
@josiahadeleke51515 ай бұрын
Honestly, I always like your program because you are always speaking the truth without any restrictions. . God bless you sir. Ogbon, lakaye ati oye ti Olorun fun yin ko ni dibaje ni oruko Jesu. E ku agba sir. Inu mi dun fun otito ati ododo ti e n so lori oro yi. Olorun yo ma wa pelu yin o. Opolopo awon eniyan ni won mo otito sugbon won ko lati so ododo. Won n gbe lehin ibaje nitori owo.
@seyioluwaseyin83235 ай бұрын
This man, Laji Abass is a highly reasonable man, very knowledgeable.
@thundero1505 ай бұрын
Ti won ba so wipe imo lo ni adini, kii se imo kurani nikan soso ni won wi o!
@abrahamaugustus16195 ай бұрын
Government should take action on him. Is an insult to the throne of Ogbomoso land
@Adekola-gu1fl5 ай бұрын
Tahun Iwo is from ekone Kogi State.... Tao wao pure igbira man
@michaeloluyemisi89875 ай бұрын
Mufti Iwo omo irankiran, ni were yi.
@aladesakiru64335 ай бұрын
eku ise sir. gbogbo igba ni moma fi opoloyi toro lodo olorun. ki olorun fun emi ati awon omomi niru opoloyi
@omolewabello34675 ай бұрын
Oloriburuku ni awon eleyi ,agbabode ni won,bi mufti se nfi owo lale ni iwo ni yunusa naa fe maa fi owo lale ni Ogbomosho Ogbomosho ni awon dindinrin yi so di yepere bee yen Ti ayilara family ba fe tun ero won pa lori yunusa tele nitori mufti yi ko ye ki won gba fun un Nitoripe elewu eniyan ni mufti eyan meji ko si le jo rinpo biko se pe won re Kini ase ti Ilu Iwo ni lori Ogbomosho Kini won si gbojule ti won fi nri oba yi fin bi pe awon ni won nbo oba yi Tani mufti legbe oba Gandy,oba Gandy to yunusa bi lomo kilo de ti awon eyan winyi ko ni ibowo fun agba,kilo pa Ogbomosho ati Ilu iwo po Dajudaju awon omo leyin yunusa ti nsepade pelu mufti lori oba Gandy ni ilu iwo Nitoripe awon oro kab iti ti mufti iwo nso wonyi o ju enu re lo Eyin christian ema wo oba yi niran ekuku mo pe ohun ija wa kii se ibon kii se ada kii si se oko E fi adura ran oba yi lowo Inumi dun pe a o gbo ibi kan ti oba yi ti soro buburu bi won ti nwe nu si to Olorun a gba ija won ja
@samyinka95655 ай бұрын
Ode Muftau to di Mufti! Ashiere alaimokan
@omofemy44795 ай бұрын
The man na igbira for real, I swear
@oyebamijimuhmeen18165 ай бұрын
No vex jare brother...🙏🙏🙏
@geraldjohn15885 ай бұрын
@@james_smith9 Talk to your brother not to overstep his boundary because he would soon regret it sooner or later. Omo eru ati alejo ni Mufti taun igbira ni ilu iwo je.
@adeyinkabolaji5 ай бұрын
Is Igbira not a human being or not a Nigerian?
@olusegunosinyomi12125 ай бұрын
This is not a matter of nigerian or human beings. A visitor in a town is a visitor, so there are some post that will l not be given To a visitor @adeyinkabolaji
@Adeolaifasoro5 ай бұрын
Even egbiras are not as insulting as this,they accord people with respect.So proud a man.
@abimbolaodunsi95735 ай бұрын
Baba wa, emi yin a gun. Eo nii ri ohun gbe sonu bi ko se ibi omo. Oro yin o ma nii daru, Sir. Thank you for being factual and sincere. Oro naa tile mba ni ninu je gegebi omo Yoruba. Haba, ki la fee fi sile de awon omo gan? Atunse ati atunto gbodo wa ni ilu Ogbomosho oh. Ire oh!
@francisoke14985 ай бұрын
it is not about getting permission from the king to travel on pilgrimage but just a curtsey of honour to inform the king. King is the leader under right and leader of the whole community but chief imam is just a religion leader.
@deedotist5 ай бұрын
Awọn bàbà wá ti sọ wípé "Ilu tí ó bá ń toro, awọn ọmọ aale ilé na kò ti dàgbà". "Ìlú tí kò sì òfin, ìjìyà kò sì ní nibẹ". Whoever mock his origin in mud, his origin will rub him in pit. Agba yin a dalẹ olùkọ́ agba Ààrẹ Laji Abass ❤
@oyelekeabidemi29725 ай бұрын
Smile 😁😁😁 wan fe teni mufti were eru larubawa omo ale ile yoruba
@OLALEKANIFETAYO5 ай бұрын
God bless you sir ❤❤❤❤❤
@olokofatai31495 ай бұрын
That's why America is great. It's built on ideas not religion, tribes or tradition. Nigeria, we are failing because we put our tribes, religion and tradition before the Nation.
@emmanuelakinola14835 ай бұрын
America original tribes have been wiped out by settlers who are now claiming ownership
@bukolaosun44715 ай бұрын
O ga o, kilode ti gbogbo awon eniyan se wa un ri awon Oba wa fin bayi? Arifin yi ti poju fun awon oba now😮 ha! O mase o 😮
@oluwafemidavid50295 ай бұрын
Oluko Agba, Adara fun yin Opoloyin oni joba. Eseun eku Ife.
@MikhailAwolowo-zm7fr5 ай бұрын
Most of the commenting did not know the protocol and procedures in Iwo. All of you should obtain a copy of the letter of appointment of installation of the Imam of Central mosque in Ogbomoso, which Imam Taliat signed before he became an Imam and read it. What is obtained in one community may not be the norm in another. That's the area most of you did not look at closely before dabling into matter that you did not have knowledge about.
@Majority335 ай бұрын
Aare, you always say it as it is. Thank you.
@aliduoladokun32225 ай бұрын
EYIN ALUFA ODE ONI E MO BA ILU JE,A BE OBA NI IMAM ILU WA.EYIN ALUFA ODE ONI ORO YIN FE SU AWON ENIYAN, E KOJU MO OUN TI ALLAH GBE LE YIN LOWO,E BEERU ELEDA, EDUMARE, ALLAH.
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Wahala mufti Po, iro nlo pa foolish man min o like Oro enu from beginning shout up Jo
@st4r._yxi5 ай бұрын
Iwo man yi, o lebi ooo , igba to je pe gomina lo nfi OBA JE NKO.
@geraldjohn15885 ай бұрын
Oponu afofungbemu ni okunrin igbira yi.
@geraldjohn15885 ай бұрын
Mufti Taun lo kowo bo nkan ti ko kan rara. Omo ale jati jati alai lopolo pata gbaa ni were yi oooo
@johnbakare67025 ай бұрын
Chief opitan soo kinni yen fun won ko yen daada. Olorun oni gba fun won ki won da ile yoruba ruu.awa oni ibo miran ti anloo.omo yoruba niwa. E jee ko yee Won daradara.
@kehindejosephkashimawo94105 ай бұрын
Mufti yẹn tí ya wèèrè.. Arífin... Kí Mufti má fún Ọba ní ultimatum.. láti ibo sí ibo??
@ditty68285 ай бұрын
It's not his fault, his sense of reasoning has been disconnected.
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Won yeye won ni, sugbon won ni lakaye bi laaji abass lakaiye lajji o ni baje
@ODUAUAEPODCAST5 ай бұрын
OMO ALE NI MUFITI IWO
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Mufti o nilakaiye Okan si awon enyen lono Oro nlo pa oleeeee ni idot man
@olawunmishafe615 ай бұрын
I blame all the obas because most of them disrespected the throne so much, the public lost their respect for the throne.
@olowojobaisaac5 ай бұрын
Mufty Iwo need mental evaluation.
@samyinka95655 ай бұрын
Very true 👍🏼
@Adeolaifasoro5 ай бұрын
Exactly, real one
@thundero1505 ай бұрын
Gbogbo oro ti Aare opitan so ninu fonran yii mu ori pipe wa. Oluko agba to tun je Onibode ile Yoruba jewo nibiyi wipe imo lo ni adini, ogbon ko gbe rara.
@adeniyitemilola25605 ай бұрын
Oriburuku ni mufti iwo yi
@kehindejosephkashimawo94105 ай бұрын
Baba kan bayi tí a npe ni Baba Jẹ̀lili, Musulumi ni wọ́n ni àdúgbò wá ní Isalẹ̀-Aké, ní Abẹ́òkúta. Tailor ni bàbá yẹn ọ̀dọ̀ wọn la sì má ngbé aṣọ school àti èyí tí àwọn bàbà wa máa nwọ̀ lọ fún ríran ..Nígbàtí baba Jẹ̀lili nlọ si Hajj wọ́n wá sí ilé wa ni Ìbarà láti wá wí fún bàbá àti màmá wa wípé àwọn nlọ si Mecca fún Hajj. Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Christian ni wá.. Àwọn bàbá àti màmá sì ṣe àdúrà fún bàbá Jẹ̀lili.. Mí ò wá rántí bóyá wọ́n fún bàbá yẹn l'owo o. Baba Jẹ́lili travel wá láti Ìsàlẹ̀-Aké wá dagbere Mecca fún àwọn parents mi. Mo rántí dáadáa.. Christian ni wá tí bàbá wa jẹ́ Ọ̀gá Akọrin ni Catholic Church nígbà náà. Baba Jẹ̀lili ni wọ́n má nran aṣọ school fún wa ní kékeré. A ti kúrò ní ilé mai rent sí ilé tiwa gangan tí bàbá wa kọ́ nígbà náà. Baba Jẹ̀lili tí salaisi ni bí 1990s yẹn, bàbá wa náà tí kú ní 1998.. Mama nìkan ló kù mo sì mọ̀ pé àwọn náà ṣì rántí dáadáa. Èyí ni lati fi kín ọ̀rọ̀ yín lẹ̀yìn.. Ko ni nkan ṣe pẹ̀lú ẹ̀sìn.. Àṣà ni..
@aminuphilip18415 ай бұрын
I have said it severely, this mufuti is the evil one behind all the crisis on imaamship in Ogbomoso. He is most likely the one who imported the so-called imaam and wants to install him by force. He just looked for a fanatics like him to create a crisis that will open the door for their evil agenda. The chosen christian king will most likely frustrate their agenda. So the battle was to frustrate or remove him from the way. Their mission is to forcefully claim Ogbomoso for the Fulanis through Islam as sponsored by Saudi and the northern Emirates just like Oluwo is doing in Iwo.They want to claim all Yoruba land for Alimi with the sword through the guise of Islam, like they did in Ilorin. It is jihadist and terrorist agenda. Imagine someone living in Ogbomoso land saying he and the Muslims are not under the authority of the king. He is openly instigating and mobilizing the muslims to riot against the king.Thank God, Ogbomoso muslims are not fools or heartless beasts.This man and his imported imaam have done more than enough to be unrobed and put behind bars.Thanks to you Aare Laji Abass and the League of imaam of Ogbomoso land for being fair and just. Islamic terrorism under any guise must not be allowed in any part of Yorubaland. The royal stool of Ogbomoso and any Yorubaland is open for qualified, suitable and matured candidate from any of the religions, but not for traitors, fanatics, thugs and terrorists. Long live Oba Ghandi the Soun of Ogbomoso. Peace upon Ogbomoso land and people.
@kazeemabdulsalam-j1m5 ай бұрын
Se ija wa laarin baba yin ati baba jelili a bi ko si ija oro yi ko fi bi kankan jo ara won rara
@kehindejosephkashimawo94105 ай бұрын
@@kazeemabdulsalam-j1m Àwọn ọlọ́pọlọ pípé mọ̀ wípé ó fi í ìkan jọ ara wọn. Àti àwọn tí wọ́n bá gbọ́ àpèjúwe pẹ̀lú làákàyè tí Ààrẹ Òpìtàn fi gbé ọ̀rọ̀ na kalẹ̀..
@Adeolaifasoro5 ай бұрын
@@kazeemabdulsalam-j1m: l wonder why some people can't just reason well
@omofemy44795 ай бұрын
That imam is so rude,and he is doing dis because the oba is not a muslim
@ibrahimoluwafemi47905 ай бұрын
Hum dont say that, you don't know why he didn't tell the king you're two judgemental you can't say that because of the king is not a Muslim, please that's not a good talk okay
@uniquebabybabygirl56405 ай бұрын
❤❤❤
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Gbe gbogbo enu e soun Alfa alabo si
@arikuyeriakanji30105 ай бұрын
Ta l’e nbawi o? Mufty Tahun ni abi Aare opitan?
@adeagboaremu10195 ай бұрын
Awon omo ti TAHUN n ko ni ibon yi yín, kini ise ti o fé fi wón sé bikose ogun jija?
@Taiwo-x3v5 ай бұрын
Tahun yi go gan, kilo ma nfi ara e pe gan? Kise ebi won
@ebunoluwa21725 ай бұрын
That mufti ìwo should be taken serious, the man is not Yoruba and he had not hide his word and intention to handle over ìwo and many other Yoruba cities to Fulani caliphate it's never about Islam but ethnic cleansing
@ditty68285 ай бұрын
One man (Bango) from Ogbomoso said mufti is from Ebiraland not a true son of lwoland. 😂😂😂😂😂
@fataihonest5 ай бұрын
Mufuti iwo Koni mon. Rara
@fataihonest5 ай бұрын
Aji abass olorun yio ran yin lowo
@chukwuemeka12025 ай бұрын
@ Mufti Iwo, E mo Pe Freedom of Religion Wa,A mo E ko Lati Fun Awon Onisese Ilorin Laaye lati Se Esin Isese Won
@imole-ayoonegod43065 ай бұрын
Eyan ma ma s'oro bi mufti bayi,won ni pe l'omo ale
@bukolaosun44715 ай бұрын
Does mufti have friends?
@Ray-cm7km5 ай бұрын
May God bless you sir. You’re right with everything you just said but don’t forget Soun was the one that make this man ridiculed him like that. He went to knee down b4 pastor for prayer so how did you expect his subjects to respect him when he didn’t respect himself and the high rank sit he is sitting on. A whole SOUN. Soun is not a small king in Yoruba land.
@folorunshoolanrewaju59145 ай бұрын
Forget about that one, that imam is so disrespectful and it's simply bcuz the King is not a Muslim.
@Topdigitc5 ай бұрын
Ko si eeyan lara a were ti won n pe ni Tawuun yen. Ka ma a ranju ran imu bi eni ti o ti fa igbo. Sio!
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Oju mufti Jo igbira kilo kan ninu Oro Ogbomosho inu mufti yen bimi eyen buruku ni omo ale baseje buruku Oloun ma mu
@st4r._yxi5 ай бұрын
Nibo ni awon gomina wa ooooo
@aruwewetv60185 ай бұрын
Awesome
@truthpeace56445 ай бұрын
Ilu tabi Ile ti o ba n toro, omo ale ibe ni ko ti dagba. Se awon eniyan yi le ri Emir Ilorin, Kano, abi oba Saudi fin bi ti Taolat ati Mufti yi? O ma se o.... Sebi won so pe esin alaafia ni Musulimi ni? Alaafia naa wa da. Awon oyinbo amunisin ni won da gbogbo re sile to won so oba ilu di yepere.
@Embeejay9185 ай бұрын
That man will be like Oluwo Muftau that steps on our culture
@francisoke14985 ай бұрын
Your knowledge is very powerful and you're very educated in analytical issue brother GOD bless. Haskalah Hahira. Tell all of them fanatical Muslims people.
@Malcolmxjunior5 ай бұрын
Haskalah hahira Oponu you can't even type JazakummuLlahu kahyran Oponu Omo traditional worshipper
@Malcolmxjunior5 ай бұрын
Baba come out you are babalawo confirm
@Malcolmxjunior5 ай бұрын
So Mufti Ile Yoruba ko Le nu Baba go seat down
@francisoke14985 ай бұрын
@@Malcolmxjunior go and ask your fore father what religion his papa was born in. oponu ayirada tell me about language or how to write.
@francisoke14985 ай бұрын
@@Malcolmxjunior mufti my foot
@bukolaosun44715 ай бұрын
Is this man called Mufti a human being? He doesn't behave like a human being 😮
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
Mufti yen o fi be gbadun dada baseje ni
@adewaleorekoya52915 ай бұрын
Mufti iwo oloriburuku nie aiye ee ma baje Nile yooba ni
@SemiuBello-th7oe5 ай бұрын
Alapansanpa o dele Olubadan Ibadan o fara ro. Eegun to korin yi fara gba gbeyingbeyin ni.
@oluseyeojo37265 ай бұрын
Ori mufti daru lati ma fun oba wa ni ojo meje
@temidaniel20235 ай бұрын
We need to look into chief Iman of this, chief Iman of that .... Are they getting some portion of money from the palace or from the government ?
@adeagboaremu10195 ай бұрын
Aràn (worm) n yo Èèrà (insect) TAHUN IWO l’enu.
@everg45695 ай бұрын
Omo ale Mufty iwo
@francisoke14985 ай бұрын
awon alfa almongiri, oju ori ola ri. Kundaru , alagba so
@ditty68285 ай бұрын
😂😂😂😂😂 alimajiri
@kazeemganiyu81605 ай бұрын
Mufti ki i se Yorùbá, nitori gbogbo oro re ko ya to si ti afofun gbe mu, ki a si mo gba gbe pe Oloselu onijibiti ni mufti odaran yi, bi ki ile Yorùbá da ru ni oma hun se, ki gbogbo agba gba ni ile Yorùbá mo bi won yo se fi mufti jo fin, nitori bi won se bere ni ilorin ni eleyi, oba 419, to hun fi esin Bo ju se ise aburu.
@everg45695 ай бұрын
It will not be better for OLUWO of IWO
@arinolamayaki74875 ай бұрын
Am sure that Mufutau iwo will soon put tolia of ogbomosho into trouble. Tolia will soon be removed. He is not a true son of Ayilara, he has bad blood of b.strd in him fighting Oba Ghandi, omo oko ki huwa bi omo ale! Ikun nde dede, dede nde ‘kun loro imam tolia!
@suadahitv16845 ай бұрын
Sebi won ni fulani leyin nan sir baba wa onpitan
@Jimmysteeve5 ай бұрын
He told them that he trace his ancestral lineage to omo oloye moyin in oyo state but they migrated from ekiti originally
@Emiola_15 ай бұрын
Ore mi ni omo de yii 43:18 😅
@adecrown44135 ай бұрын
Yoruba. O ma su Mio. Hahaaaaa. Yoruba.
@SemiuBello-th7oe5 ай бұрын
It's very unfortunate in Yorubaland that our people are bringing sentiments to many things. The same organisation wrote a letter of threat to my school to charge my school to court because of one of our students who comes from Iwo. By the end, the so-called boy eventually turns to become our friend.
@OLUWASOLAOLADEPO5 ай бұрын
nnkan mase iran yoruba bayi oo, ipo oba ko wa ni ola, aponle mon. ko wa si aponle mon. oba lo ni ilu, olori ilu, awon alfa, pastor are messanger and servant they are subject to king
@bukolaosun44715 ай бұрын
This Mufti yi needs to be called to order by the Government. With all the nonsense his saying he needs to be arrested.😮
@OLUWASOLAOLADEPO5 ай бұрын
this mufiti iwo ko ni opolo rara, eyn omo ogbomonso pls talk to this mufiti mufiti that does not get sense
@OLUWASOLAOLADEPO5 ай бұрын
this man mufiti is senseless and you can still caursing pepople
@temidaniel20235 ай бұрын
Governor Ambode removed state chapel reverend in Alausa
@SemiuBello-th7oe5 ай бұрын
Remember the imam that was removed in State House Abuja.
@bayosammy5 ай бұрын
Government suppose to arrest this guy called Mufti as soon as possible.
@Eniiyi.5 ай бұрын
Muslims dont want to respect our traditions but when they travel south they respect emir and bow, because they are superior to your own king ? Can any Christian leader talk to the emir of iwo like that ? Forgetting your origin because of religion ? So because hes a Christian the imam can travel without permission and telling the king? If anything should happen while the imam is jot around who will take responsible if not the king.
@tijaninafiu12775 ай бұрын
Kabiyesi can never remove Imam in Saki and TEDE not only in Ibadan sir
@bukolaosun44715 ай бұрын
Why is Iwo people not taking concerning all these rubbish that this man is saying.😮
@everg45695 ай бұрын
He truly looks like Igbera
@francisoke14985 ай бұрын
ob ba lori ohun gbogbo
@kareemajibola19355 ай бұрын
Maa paro mon,fii video yen han,ibi tii oniwo tii soo pee onisese nii oun naa?
@folorunshoolanrewaju59145 ай бұрын
Omo ale Yoruba nie, for saying this man is lying, it has been a long time since he posted the video, you should go online to Google it and stop being disrespectful.
@ayobamiayobami59065 ай бұрын
I even watched it, so stop saying rubbish
@OdunugaAdeyemi-u4e5 ай бұрын
Onpitan are you from this world.Can't hear that Soun have banned Chief imam from the palace and he was not to enter or interfere to palace activities since February 2024.
@fataihonest5 ай бұрын
Olorun a ma ranyin lowo o
@Malcolmxjunior5 ай бұрын
Ori babayi tidaru gan ooo. Oponu baba
@francisariyo77545 ай бұрын
Gov Ambode suspended the state house chapel during his term
@aysiaajoke99555 ай бұрын
Mufty yi ma mu Igbo,eniyan radarada ni man yi ooooo
@st4r._yxi5 ай бұрын
Iru arifin wo re, Olorun sanu.
@abrahamaugustus16195 ай бұрын
lf l were the Soun of Ogbomoso,l would dethrone him as Imam of Ogbomoso.
@AkinolaFaosat5 ай бұрын
E wo e Fi mufti ode yen le ko ni lakaiye I don't want to hear him
@francisoke14985 ай бұрын
silly scholar omo oko alfa very rude
@adeyinkabenjamin47865 ай бұрын
Very stupid mufti
@TimTechA3L5 ай бұрын
Aare please sir forget about that senseless man. He’s just looking for relevance among the Muslims. Noise maker.
@tijaninafiu12775 ай бұрын
I'm totally disagree with you with some point her sir
@OdunugaAdeyemi-u4e5 ай бұрын
You lied ,not only in ibadan that 22:59 23:09 olubadan didn't appoint imam