Awon enia to Japa won ko ohun ti o nsele leyin odi. Bakanna won ko fe ronu ipenija ti o buru jaye. Sugbon o ye ki won Bere lowo eleda won ki won to gbera so. 😮
@OlaideOlaifa5 сағат бұрын
Orileede Yoruba laaa feee oooo, ohun nikan lona abayo.
@TobiOjo-qh5fu5 сағат бұрын
Ilu wo ni eleyi ma
@christianahomosola84356 сағат бұрын
Osoro lori fulanis tona pa omo Nigeria lojojumo.
@anointed584111 сағат бұрын
Yoruba nation nikan lona abayo.
@akinwaleolufemi918611 сағат бұрын
KOSI WOLI, TABI ALFA, BABALAWO KANKAN TI YIO SO OTITO ORO FUN ENITI OFE JAPA NITORI ANFANI TIWON YIO RIGBA LOWO RE TI O BA JAPA.