By the Powers In D BLOOD Of JESUS CHRIST, I Connect Alll my Family, Our Loved Ones & MySelf To ALL. These Godly ALTAR PRAYERS, In Our LORD SAVIOUR's Mighty Wonderful Perfect Peaceful BLESSED Name, AAAMMMEEEN
@adeyemiileaje42387 сағат бұрын
Ni oruko Jeesu, gbogbo omiran oru to n yo aye mi lenu, to n yo aye awon omo mi lenu, Oluwa ba mi sa won pa, omiran oru to n yo aye awon omo mi lenu, Oluwa fi ida ina sa won lasapa, Oluwa kolu gbogbo awon omiran oru ninu aye mi ati awon omo mi loruko Jesu,
@biodunfemi623011 сағат бұрын
Ofa jade Lara mi taya tomo loruko Jesu Kristi 🙏🙏🙏
@adeyemiileaje42387 сағат бұрын
Ire awon omo mi ti awon ole fi oru kole, Oluwa da pada, iserere awon omo mi, ogo awon omo mi, ti awon ole fi oru ko le, Oluwa da pada loni, fi aanu da won pada fun loruko Jesu
@fatimalassissi64157 сағат бұрын
Amen 🙏🙏🙏🙏🙏 Amen jesu
@estheroladunjoye513810 сағат бұрын
Hallelujah x 63 💞💞💞😁💞💞💞
@adeyemiileaje42387 сағат бұрын
Gbogbo eranko abami to n di ire mi lowo, ina Oluwa jo won danu loruko Jesu
@FadipeOseyemi10 сағат бұрын
I connect myself my children my sisters and brothers to this powerful program Ijn 🙏 amen
@tojuadeayoola120910 сағат бұрын
Amin LORUKO jesu
@OlatinkanVictoria8 сағат бұрын
Aminloruko jesu
@AlakeOlufunke9 сағат бұрын
Oluwa e seee oooo lori aye mi lori ile mi oluwa mo dupe