ỌRỌ YÌÍ TIDI OGUN ỌTÍ DI JA OOO OMO YORÙBÁ EWA GBỌ
Пікірлер: 45
@adebowalenathanieladedeji1718Ай бұрын
Gani Adamu jé onilara enia ti òwò ti jèraba é. Òwò ni Gani nlé kiri, oté ati tènbèlékun ni Gani nba Kiri .
@user-jg1fw5xj1iАй бұрын
Up Oduduwa Republic! Up Yoruba Nation! Yoruba Nation Now! Yorubaland is a task and a reality that must be established.
@user-ue3ew6lq5sАй бұрын
baba ekiti ayeyin oni baje oro yin oni daru amin olorun awola iru emiyina timioje nkankan yina awola ojo meje ti mofi gba awe Lori majasola owo ota onika majasola
@SuruAlfredАй бұрын
Baba ❤eku eto olorou away pelu yin
@user-wj9nv7de8lАй бұрын
Sunday igboho ati enyinna e ko ni subu o lagbara olorun oba oga ogo aamina kunfayakun aseniti edumare aaaseee
@abetoba2331Ай бұрын
Truth talk, may God bless you BABA EKITI,
@nathaolu5600Ай бұрын
Good job
@dolapoadeoshun1370Ай бұрын
Baba Ekiti aiye a yè yin o. Yooba o ni gbagbe rè ati MAJASÒLA pèlu gbogbo èyin t'è ñwa ominira fun iran Yooba. Asèda aiye oun òrun yio ranti gbogbo yin si rere l'agbara Olodumare. Gbogbo wa la o jò de'lè ileri na l'asè awòn Adèda. Ride on the Lord God of Heaven and Earth will ever ever be with us in Jesus Name . YOOBA NATION NO GOING BACK.
@KehindeoseniSaliman-ou4jtАй бұрын
YORUBA nation no going back EKU eto sir ooo baba mi Lekiti eku ise takun takun sir ooo emiyin yio gun ni agbara gbogbo awon ALA Len Ile Yoruba patapata ooo
@kolapoadekunle8587Ай бұрын
God bless you sir, you're saying the truth....by God grace YORUBA NATION will STAND ❤❤❤❤❤❤......
@aderibigbematthias8646Ай бұрын
Baba Ekiti Oluwa yoo kun yin lagbara o, e ku ise o.
@omoyelesamson2150Ай бұрын
Babal'Ekiti I praise your courage. E kú ise o. A o se aseyori. Ile yoruba yoo da duro laipe lagbara Olodumare. Onigbaraga ènìyàn ni Gani Adams.
@tundealabi5217Ай бұрын
You're on point, Baba Ekiti. I love you, Baba Ekiti! Keep it up! Ganiyu is bound to end in doom, ignominy, and disaster!
@olayioyesamuel858Ай бұрын
Ese baba ekiti God bless you sir
@margaretibijoke4973Ай бұрын
Baba ekiti, e o ni se lasan o, Olorun yoo je ko lesan rere.❤❤
@banjiwilliams4394Ай бұрын
Baba Ekeiti Oye ki won Fun Obirin kan jade lati ma pe Sunday loruko je
@geraldjohn1588Ай бұрын
Ile t'oba ntoro,omo ale be ni ko tii dagba. Omo Ale nii fi owo osi juwe ile baba re,bee gege ni Gani Adamu ri.
@margaretibijoke4973Ай бұрын
Are ona ajegbadun,are arogunsa 😢😢
@obafemikings7879Ай бұрын
Baba Ekiti, e ku ise takotako, 'sir'.
@iretiebiesuwa9071Ай бұрын
E ku ise takuntakun
@MrBajos-ce9byАй бұрын
Baba Ekiti, my guy. You will not kill me. I love you dakuest. Gani must apologise publicly and voice recording. Otherwise, the court will be the last solution. He is too arrogant and disrespectful.
@mygodisgreatt.elizabeth2091Ай бұрын
Baba Ekiti you are very weldon sir, don't mind that useless gani, Yoruba Nation no going back.
@olusolaayindefakeye4426Ай бұрын
Gani Adams must apoologize to Chief Sunday Igboho before it is too late.
@AyotundeOlaoye-wg4biАй бұрын
One Nigeria is a scam is also a slavery life suffering life and hardship life.
@adewilliams8Ай бұрын
CORRECT!!!
@olusolaayindefakeye4426Ай бұрын
Mo gba patapata lori oro baba Ekiti wipe Gani Adamu gbodo toro idariji lowo CSI nitori iro to pa mo o
@maryogunkuade2560Ай бұрын
That woman omọ obatala should be tagged in the lawsuit too. She seems to even know more than Gani, because her own accusations were so emphatically pronounced, as if she was always at the instance of all those said offences.
@kellyadeloye7468Ай бұрын
Baba ekiti God bless you sir that man must be dethroned immediately. He is the original enemy of yorubas. He committed hate crime
@abdullahiisau7651Ай бұрын
❤️❤️❤️❤️💯💯💯💯
@tawasaba7439Ай бұрын
E continue
@user-xg3rw3pp4wАй бұрын
Gani adamu kolo gbe emi igberaga two sile,
@user-nj3qx4xh2dАй бұрын
Baba ekiti ohgbo kankan ooo🤣won ti geh leti looo🤣🤣🤣ASAKE
@ahmedadeleke1722Ай бұрын
That accusation is too much and dangerous. Other tribes are already accusing us of being the ones killing ourselves and accusing the Fulanis. Because of what the Are Ona KankaOfo of Oyo claiming Chief Sunday Igboho killed Bola Ige
@AyotundeOlaoye-wg4biАй бұрын
Inkare baba inkuise o
@vestimash620Ай бұрын
Thank you sir, I like your energy...Ganiyu Adamu is too arrogant n he need to be charge for defirmation of character....èyìn njò rice òshi
@AyotundeOlaoye-wg4biАй бұрын
One Nigeria is making Yoruba to hate each other's
@margaretibijoke4973Ай бұрын
Only God knows how yorubas got to the point of been blindfolded with crumbs 😮😢
@idowuaderemi1370Ай бұрын
BABA EKITI OOO,AWON YORÙBÁ NI WON NI PE ILE TI O BA TOORO ,OMO ALE IBE NI KO TI DAGBA ,A BA NI JE NI AWON OLORI BURUKU OMO ALE GANI ATI PE OWU JIJE NI O PA GANI YIO ,E JE KI BABA WA SUNDAY IGBOHO MA BA SE RE LO ,KI AWON OMO YORÙBÁ E JE KI A FI OWO SOWOPO LATI GBA ASE ILE WA OO
@HamedSalawudeen-uu7qhАй бұрын
Babaekiti timobaje obirin emi kobafeyin
@HamedSalawudeen-uu7qhАй бұрын
❤😂❤😂
@ajayiadeniyi4030Ай бұрын
You are just too much baba Ekiti, Ganiyu Adamu must bow to Yoruba people if not ...
@marcusakinseye520Ай бұрын
So is it Gani Adam's matter that you are all worrying yourselves about ? Pls let's be focus fulani are entering our lands on daily bases babaLekiti let's forget this
@ibrahimoluwafemi4790Ай бұрын
You're right but this is not something we can forget about not because of today but because of tomorrow, we can't accept anybody to tannish cheif sunday igboho osa name because he's only one man that we see when yoruba land is very scare to stay okay
@igbasantoyin8176Ай бұрын
Baba ekiti pls forget this bastard even if he retract the statement or apologize to oloye Sunday igboho oshaa.he will face Court and detrone him