Markaz Agege ati Daru Dawah Isolo ko ni baje laelae , Pelu ogo Olohun Aamin Thuma Aamin
@OlaniyiSikiratou2 сағат бұрын
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
@issajimoh270114 сағат бұрын
Alihamdulillahi Alihamdulillahi Alihamdulillahi Olohun ba wa se alekun emi gigun, alafia, ifokanbale, idunu, arisiki ati alubarika fun gbogbo eyin Baba alubarika Ki Olohun ba wa se alekun ike ati ige fun awon agbalagba wa ti won ti lo ati gbogbo oku Islam Eyin gbogbo won ko ni baje laelae