That is not a problem, DSS will need to arrest mufti, Nigeria government is creating problem for future generation. No nation govern with religion can survive
@davidtumiariyo15 күн бұрын
Muslims own DSS. The results of Muslim ticket
@olabanjofashakin154315 күн бұрын
I agree with you my brother.
@olowojobaisaac15 күн бұрын
Esin were ni esin Islam.
@aderinoyeadesanya968015 күн бұрын
Where in Nigeria was it stated is a criminal offence to burn quran or bible. Let God fight for himself.
@olatidoyeolaniran530614 күн бұрын
@@aderinoyeadesanya9680 There's actually blasphemy law in Nigeria constitution, though, there's no real definition for what blasphemy means... and I think the vagueness of the blasphemy definition is what the Islamists are banking on. Nigeria is a secular state and a secular state is a state where anybody is free to choose and criticise any god but I don't know why they include blasphemy in our constitution.
@deleogunniyi419115 күн бұрын
Eledumare is a good God, he doesn't punish anyone
@horlarhorlar607715 күн бұрын
I am just tried of injustice in this country called Nigeria
14 күн бұрын
This is just a drop in the ocean🤣🤣🤣
@LewisMuturi-b7u15 күн бұрын
Oloriburuku ajeji omo irankinran Gambari-Fulani
@bakarekazeem236815 күн бұрын
Musulumi o le ku pe. Iro ti ba aye won je. Honestly, these people keep causing hatred for themselves
@kamaldeenaolatunji728215 күн бұрын
Bakare kazeem.. not muslim, y not change ur name to ifakorede
@niniolaolamilekan827515 күн бұрын
TANI OLOHUN OLOHUN BLESS YOU 🙌 🙏 ✨ ❤
@ojesjonathan656615 күн бұрын
Oni sese don't have level, in Yoruba land, there is much work for oni sese to do, it more than online talk. You guys need good lawyer Incase of days like this.... Nigeria don't recognize oni sese but our law have space for it.
@abiodunoyewole525815 күн бұрын
You talk good sense here ❤❤❤
@ojlinksglobal161615 күн бұрын
Tani Olohun charge this man to court he said you conspire with the guy and said that you are member of Odua Nation. Kindly arrest him asap for defamation of character
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
@@ojlinksglobal1616 U want to bati Tani Olohun je patapata, if The guy gets arrested again....
@UrFavBaconGirl15 күн бұрын
The alfa speaking is a foreigner in yoruba land.The name implies
@binaryworld400015 күн бұрын
Fulani ni won
@AbdiDanMakarfi15 күн бұрын
Tori Oloun; ewo lo kan DSS pelu burning of the Qur’an.
@babatundesokunbi327415 күн бұрын
I wonder o
@BenjaminAdedapo15 күн бұрын
I don't know
@saheedsolely140715 күн бұрын
This so called Alfa were too stupid
@KaflatKaflat14 күн бұрын
😂😂😂😂
@IlesanmiSunday-ji5sy15 күн бұрын
I don't think Nigeria we ever work because burning ordinary paper and got arrested and they will allow someone that burn human being to work free
@deleogunniyi419115 күн бұрын
No, your belief is a foreign belief
@maryogunsina506615 күн бұрын
Elebo lo ma ri eyin yin insha allahu
@Novikedocumentary15 күн бұрын
Any Muslims that talk bad about traditional religions should be sue are arrested.
@BenjaminAdedapo15 күн бұрын
Identify one or two persons and charge him to court for violation of rights.
@amoscoker88215 күн бұрын
Ki Olodunmare gbawa lowo Allah
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
Eyin Elebo Alailenikan Niyin, Omo-orukan Niyin o . Eyin Naa Oyeki Eledanuro pe koyeki Emafi Oribale fun Irin machine,Egboro keke Tabi sare Baba n la yin Oyeki ELO da Olohun tosedayin mo Ni. Olohun yiofi yin Mona Otito o.
@binaryworld400015 күн бұрын
@@OlawuyiRoufye so Yoruba lęnu omo ale. So ede larubawa eru arabu. Allah kise olorun. Allah eyin musulumi bę ninu kaaba 😂 eyin musulumi abor okuta Quraish eru allahu.
@KaflatKaflat14 күн бұрын
@@OlawuyiRoufoponu ayirada dindinrin, China olushina ni won .
@walesal790615 күн бұрын
Awon alfa Nigeria koni itiju kan pa, opolo ori won ti ku patpata
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
Won bo wa gbe 'wo Naa. Awon irunmole yin ti n serve punishment Ni Orun Eyin Elebo tiwa di Omo-orukan .
@FagbamigbeEmmanuel14 күн бұрын
@@OlawuyiRoufI pity you, you have bn brainwashed your son won’t be like you Ase
@princeshanusi320115 күн бұрын
Konida fun awon tobi e,,konida fun anobi Muhammed.
@princeshanusi320115 күн бұрын
Nigeria government should stop this people now before whe yoruba people will react.
@princeshanusi320115 күн бұрын
This stupid idiot what is your concern about his religion.
@ojosamuel112315 күн бұрын
Because of China printed book
@michaeloluyemisi898715 күн бұрын
Mr man Allah loni Quran, ki se olorun oba ti wa.
@adeade24215 күн бұрын
If Quarah owed by Allah. Why is Quarah printed in China by idoll worshipers
@lindalondon-tz9sw15 күн бұрын
Esin were inun won o dara rara
@abiodunadeyemi629015 күн бұрын
Tani olorun pls look for more lawyers to fight for isese
@jamesshall516015 күн бұрын
Anywhere in the whole world the duty of the Department of state security is to conducts international investigations, counterterrorism, and criminal investigations but in Nigeria, the duty of the DSS is to harass and intimidate innocent citizens! What concerns DSS with Koran or Bible? Awon oloriburuku gbogbo. what a lawless country?
@Sankara80-v5f14 күн бұрын
Dogpemu stupid service!!!
@josepholatunji712614 күн бұрын
Ki lo buru ninu ki Christian ati musulumi darapo mon Yoruba Nation, Yoruba Nation yii ti gbogbo Omo Yoruba patapata ni, ayaa fi awon adamodi, awon atounrinwa, awon Odale, pelu gbogbo awon ti iye won ti ra nikan lo lee tako Yoruba Nation won kan momo ntako isheda won ni sugbon ki won mura si, iba ti dara to ki won tete tun eroo won pa, kie tun wa gbo Yoruba ni Isheshe, Isheshe ni Yoruba lo'jo gbogbo, Isheshe a gbe wa, Oodua a gbe wa ko ni gbe Odale, Tani Olorun mo ki yin tokan tara e ku eto, ma gboo yin pe la'gbara Eledumare.
@maryogunsina506615 күн бұрын
Awa Elebo la ma ri eyin yin ,Alale Yoruba ni yoo se yin yanmon yanmon.
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
@@maryogunsina5066 Alale ko Omoale Ni! Nonsense .
@gbemisolalawal575813 күн бұрын
❤❤❤❤
@maryogunsina506615 күн бұрын
What these daft fanatics don’t realize is that arresting these onisese people is like promoting the religion more, is like our eyes are been opened day by day.
@femiadebayo799715 күн бұрын
Tani olorun, pls open one account for we that can pay money to, to a get lawyer for him no token is small pls
@olatidoyeolaniran530615 күн бұрын
We should push for the removal of blasphemy law in Nigeria. Nigeria is a secular country for christ sake!.
@Sankara80-v5f14 күн бұрын
Look Nigeria is not a country at all, it's a lawless contraption on the verge of total break down. To get our separate yoruba Nation is the only thing senseble.
@olatidoyeolaniran530614 күн бұрын
@@Sankara80-v5f Who burn Deborah dey free, who burn Koran dey jail!
@sunshinesm565715 күн бұрын
Kinni yoruba nation niise pelu esin nitori olorun eyin Alfa yi. 😢😢😢😢 E ma je ki gbogbo ile ibadan je illiterate nitori olorun oba.
@babatundesokunbi327415 күн бұрын
Koyemi rara o
@michaeloluyemisi898715 күн бұрын
You just listing to your self, eyin alakatakiti esin oriburuku.
@DavidBryan-gj7yx15 күн бұрын
More is still coming
@davidtumiariyo15 күн бұрын
Mr man. What do you mean? More are still coming? Do you want more or what? Sorry, please?
Tani Olohun reports the case to pastor Takuti Jesu let all your people Isese standup to recuse this man..Olorun yio gba agbara kuro lowo awon alakatakiti elsin Arabu Arebia wonyi.
@ola-oodua249914 күн бұрын
The awakening has come to stay. There is little anyone can do about it.
@lawrenceonuorah601915 күн бұрын
They missed the teaching. What that man burns is paper, not the word of God. The word of God is the content in that paper which nothing can change
@kamaldeenaolatunji728215 күн бұрын
Yes, that's the paper containing the words of God,the burning was solely provocative, if Muslims react to the actions, I blv u know it won't b funny.
@bijianobijiano493215 күн бұрын
Hmmmmm. I can see war happening in Yoruba land soon 😢😢😢😢😢😢
@oluwafemijohnmiracle987715 күн бұрын
Asè Asè Aseedumare. .. it soon happens.. couse without a war nothing can change nd Muslims must pays for all of it
@oluwolesodipo764015 күн бұрын
What concerns does DSS have about religion?
@olabodeolajuwon431815 күн бұрын
Eyin onisese le o dide lo report nitori awon musulumi lo Fi ejo sun Ni won Se mu yin eyin Naa e lo pe won lejo
@davidtumiariyo15 күн бұрын
Muslims own DSS. The results of Muslim ticket.
@almightyjagaban893914 күн бұрын
Oko awon musulumi.. Eledumare go bless the cameraman
@jubrilsaheed341615 күн бұрын
I hope the guy come out safe 😢
@binaryworld400015 күн бұрын
Dindinrin, omugo, omo eru ni oba Yoruba ti o ba si nse islamu. All these mumu Muslims will just dethrone our yoruba king one day if care not taken, its all agenda to take our land. Say no to islam.
@ABLEGOD202411 күн бұрын
Those people have problems
@DayoAdewale-os3jz15 күн бұрын
SE olorun no DSS no EYIN OMUGO wONYI
@BassirouGouverneurAllade15 күн бұрын
Olori buruku alfa wo ni o nsoro yi se quran baba re ni o sun n'ina ni tabi quran eyi ti o fi owo ara re ni o sun n'ina
@oluwasegunadeyemi714015 күн бұрын
Any hardcover textbook will burn easily unless you separate it one by one
@abrahamolayemi380215 күн бұрын
Alabosi ni man yi jare
@Pelumi-wz5fx15 күн бұрын
I asked the spirit that, what was revealed that to me some months ago, about "the beginning of the end of Islam" , I was like, Islam hasn't ended yet, but I was reassured and I heard again that, "Olowo eko, MS baba are still playing with these Muslims, that the worse is yet to come. and what Olowo eko, MS baba and co. Came to do is just to first enlighten and warn people to change or abandon that religion (Islam).. but this time for those that refuses to listen and change, then the gods wouldn't need to be blamed for what will befall them. And again I heard, history is about to repeat itself, but this time with serious consequences. I guess this is the period it will happen. Happy viewing.
@adewilliams815 күн бұрын
Omo ale eru Hadi. Gbogbo awon ota Yoruba nation won koni ku ni re. Eyin imale ti e n se ote Yoruba, eyin ati iran yin ko ni bo l'oko eru lailai. Ase!
@OladunniAkinwunmi-x8o15 күн бұрын
Ejo ebawa gbe gbogbo video ibi ti won ti sun aso egun ati awon nkan isese kofi DSS gbe won
@deleogunniyi419115 күн бұрын
Iya Nigeria ma jeep dada
@abiodunadeyemi629015 күн бұрын
You are using your power he bought it himself ko le jelo nile Yoruba eyin eran won yi
@DavidAdekunle-r1b13 күн бұрын
Ijoba lo ma da ogun Esin sile, bi Ijoba ko ba kiyesara.
@omofemy447915 күн бұрын
My problem with Isese people is that una no dey arrest na dem dey arrest una
@DavidAdekunle-r1b13 күн бұрын
Nibo ni ofin Nigeria ti so pe o lodi lati dana sun Quran? Eyin Aafa lo nda ilu ru.
@gbadeboiyabo49315 күн бұрын
Opolo alfa yi ti lo, Oloriburuku ni gbogbo yin
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
Se Aduru Baba yii Ni Osope Opolo re ti lo atipe Oloriburuku tun Ni gbogbo yin? Otiyewa pe Oni Ogbon, gbogbo Awon Agba ileyin tiku niyen.
@KaflatKaflat14 күн бұрын
@@OlawuyiRoufogbeni tie poo hoo,kin lon wa Lori plat form awa elebo.abi tie fe ye ni.musulumi egbe re melo lo ri ni bi
@YusufOlohunkemi-t6y12 күн бұрын
Oma se ewon ku ni
@truthevolving80015 күн бұрын
If you, Onisese, don't talk, nothing will happen. If Musulumi talks, something will happen. Onisese should also petition the government against the excesses of the Muslims.
@maryogunsina506615 күн бұрын
Alfa yi ko ni ye yin sir, oloriburuku omo fulani , ese eran ma ti wa dapo Mon ti eniyan ni ile Yoruba.
@falohunibrahim63314 күн бұрын
I don bunt quaran befor complet
@maryogunsina506615 күн бұрын
Oloriburuku onirungbon obuko.
@mayowaidowu708114 күн бұрын
"Nibo lowa tolohun o lemu o" se Olohun lowa mu?
@MoshoodMalik-j6z14 күн бұрын
Oloriburuku ni awon eru larubawa yii.. Elebo ton pe enikan lelebo
@KaflatKaflat14 күн бұрын
Ode ni won ni.eran agbo ti won npa ni odun ileya se kin se ebo.
@mayowaidowu708114 күн бұрын
Se ilu e ni igbo oro wa ni? Abi iwo je yoruba?
@kazeemadewumi-tm5ro15 күн бұрын
Ogun loma pa alfa ti ohun paro yi tori pe ilekeu ni won ti sofun wa pe kurani kolejona
@kamaldeenaolatunji728215 күн бұрын
Talo so fuyin be, either you or the alfa didn't know at he's saying.. The item it was made from ìs flammable.
@KaflatKaflat14 күн бұрын
😂😂😂😂
@Kantz114 күн бұрын
Àwọn Alfa onirọ. Nigbati Allah ò jẹ ki Kurani jóná mọ́’lé, ki lo fàá ti Allah fi dakẹ ki ẹnikanṣoṣo sun Kurani jona patapata? Allah lagbara lori iná, ṣugbọn agbara Allahu kò ká ẹnikanṣoṣo!! Lori irọ lẹsin jàgídíjàgan. Ẹyin ṣe njà fun Allahu? Ṣe nitori Allahu yin kò lè jà fúnra rẹ ni? Báwo ni ẹnití o sun Kurani tó fi owó rẹ̀ rà, ṣe tẹ̀ yín mọ́lẹ̀? Ẹ̀yin ẹlẹ́sìn agídí.
@Kantz114 күн бұрын
Àwọn Alfa onirọ. Nigbati Allah ò jẹ ki Kurani jóná mọ́’lé, ki lo fàá ti Allah fi dakẹ ki ẹnikanṣoṣo sun Kurani jona patapata? Allah lagbara lori iná, ṣugbọn agbara Allahu kò ká ẹnikanṣoṣo!! Lori irọ lẹsin jàgídíjàgan. Ẹyin ṣe njà fun Allahu? Ṣe nitori Allahu yin kò lè jà fúnra rẹ ni? Báwo ni ẹnití o sun Kurani tó fi owó rẹ̀ rà, ṣe tẹ̀ yín mọ́lẹ̀? Ẹ̀yin ẹlẹ́sìn agídí.
@BabalolaSam15 күн бұрын
You guys burnt innocent Deborah for just a word about Muhammed as if youve all seen muhammed before. Nothing was done. That was life, human like you. But with Paper 📜📜 and you are all doing all these? 😱 😱 OMG!
@abrahamolayemi380215 күн бұрын
Ki e fe so sinawon ti won n dana Sun ekun eegun ati orisa
@olatunjifredrick819215 күн бұрын
The more you look the less you see. 9ija case .
@tolulopeoluwole948514 күн бұрын
People need to show respect for other people's religion. If you don't like it, don't touch it, talkless of burning it. Let's be civil and avoid provocations
@marianosinubi778915 күн бұрын
Kini kan DSS pelu Esin ile Yoruba. Kilode ti Awon Musulumi se je oni wahala pelu aini isinni ni orile ede wa
@binaryworld400015 күн бұрын
Eru fulani eru larubawa ni awon musulumi yen, musulumi lo gor ju lagbaye.
@maryogunsina506615 күн бұрын
Eyin alakatakiti musulumi inu igbo ni ile yin, w ko ni jere.
@maryogunsina506615 күн бұрын
Dss se ko fe ye yin ni?
@princeshanusi320115 күн бұрын
Must of you Alfa as know brain.
@olalekanopeyemi184315 күн бұрын
You guys need protest
@temitopemartins117615 күн бұрын
Gbogbo awon Afa yen koni ise rara eyan buruku niwon , ko seni to le gbeja OLORUN , paapa Nile yoruba /Gbogbo iwa ibaje arin won lowa ninu family mi Gbogbo wa musilimu ni sugbon celestial church lemi nlo Gbogbo wa si jo nse po ni , awon onisese ninu family we're all doing things together/
@deleogunniyi419115 күн бұрын
How many bible we have seen not burn in fire
@E.wakanda.U-S-Afrca15 күн бұрын
Over 10 quran lo jona ni adugbo mi nibi odun die seyin 😅
@joshuaomoleye669715 күн бұрын
WHEN YOU KNOW GOD WILL CASH HIM, WHY NOT LIVE HIM ALONE WITH THAT GOD. CANT YOU PEOPLE ALLOWED YOUR ALAH TO FIGHT FOR HIMSELF.
@peterfernandez751115 күн бұрын
Se bi musulum sun bible ,se awon oni church mu ni
@babatundesokunbi327415 күн бұрын
Awon elesin christen gbon ju awon elesin alakakiti eru Arabo
@BabalolaSam15 күн бұрын
Kini Aburu ti o se? Na wa ooo.
@AbosedeCaroline15 күн бұрын
See this guy brain 😂😂😂 alfa oni tinted hair 😂
@generalman301615 күн бұрын
Let your alau defend himself is he powetrles? He burnt the book he bought with is money how is that a problem
@abiodunolawoyin977415 күн бұрын
Ni won ti awon olote agba ofo Yoruba ti gba awon won Yi laye lati ipinle wa,kosi ani Ani kankan,afi ki awon irunmole oja fun Iran omo alade
@johndada350015 күн бұрын
U all see that sheria law is coming
@OlawuyiRouf15 күн бұрын
@@johndada3500 sharia law good.
@abiolaganiou205115 күн бұрын
Tani oloroun!!! Kosi sisé kosi ayi sé Gbogbo wa ki abéré sii maan djo Coran ni nan lodjo jumon. Lodjo jumon ki a maan djo Coran ni nan.
@binaryworld400015 күн бұрын
Beni gbogbo ma jo kurani ninan lekan nan. Esin ofo esin ikonileru ni islamu
@OladunniAkinwunmi-x8o15 күн бұрын
Ise yanu wo ni story book ti awon china bawon te abi elebo koni awon china
@walesal790615 күн бұрын
Ejo wewe wo ni alfa oloriburuku yi wa nro bayi? Se iwo loni kurani ti won sun ni? Se kurani ti e no ti jona ni? Sebi ohun lo fi owo ara e ra kurani tojo nina? Ede je ki Olohun ja fun ara e, abi ewo ni fifi owo agbara fiya je eni ti ko Se ese kankan, Nigeria is a fraud honestly.
@alabirasaq828715 күн бұрын
Koni bon be
@yarocomedy588115 күн бұрын
OLORIBURUKU AYE ORUN NI AWON ALUFA YI,ENIJERE PELU QURANI YIN ELENU WOYOWOYO
@WaleWale-d7y15 күн бұрын
Ori awon alfa ti buru pata pata . Are they from Saudi that they are fighting for useless Allah ?
@kamaldeenaolatunji728215 күн бұрын
He's looking for fame ne, like ù, he wil be surely famous.
@Dare-d7h15 күн бұрын
IRO LASAN Arabo levels 🤣
@luqmanbisuga942614 күн бұрын
Oro rirun lenu asiere alfa
@adekunleezekiel290115 күн бұрын
Lati je ki ALAAFIA joba Nile YORUBA,ko si ntoburu nipa IPADE ti elesinmeteta se. Mo ro eyin ti e wa nibi ipade yen,e tunbo tera mo ipade yen , but e fenuko Lori awon to ba n ba esin miran je ijiya toto fun won,KO si gba house of assembly gbogbo ile Yoruba koja. Ki wahala yi le dopin.
@adekunleezekiel290115 күн бұрын
KO si eni to le ja fun Olorun. Iwe to dana sun,e je kolorun je niya FUNRARE. Tan ba Dana sun Bibeli I bo leti gbo pe Kirsten ti GBOGUN dide nitori re Musulumi e jawo ninu apon ti o yo. Tiyin lo ma nbiyin ninu,ojo te ti nbu enu ate lu ONISESE ATI Kirsten won ki nsoro,kilode te GBE esin kari bi eleyi.