HYMN 237 Emi Mimo Olutunu Sokale sarin wa Ire Oba Olubukun Awa nse reti Re Nitoripe Ire ni Oba Nla Oba Olore Oba Emi sokale wa Awa nse 'retiRe Oba anu sokale wa Si ju anu wo wa Awa omo Re nwo 'ju Re Silekun anu Re Oba Mimo, Oba Olore Baba 'jo bukun wa Nitoripe Ire l'oba T'o bukun omo Re Oba anu, Oba Iye Tan 'mole Re fun wa Ire Oba kiki mole Awa nse reti Re Oba Mimo Oba Iye Jowo wa bukun wa Nitoripe 'Re 'Oba anu Awa nse reti Re Emi Mimo Emi Olore Awa nse reti Re Oba Mimo sokale wa Wa gunwa sarin wa Amin
@oluwaseyioluwapademi84105 күн бұрын
If only celestial members can know, understand and live for what God Almighty created CCC to be, everyone will fear God, live holy and the whole world will be cleansed through CCC.