Laji abass eku eto, yio yẹn yín o, a dẹ ku igbaradi silẹ fun "Itan Àwa Yorùbá" ti yio w'aiye lai'pẹ. Ọjọ ayọ ni yio jẹ l'aṣẹ Olódùmarè
@yunusobashola95957 ай бұрын
Aare God bless you so much sir. you're doing a great work for our tribe 👏
@RasheedatAkinloye7 ай бұрын
A ku imura. Ibi ko ni sele si enikeni siwaju ati ojo ati leyin ojo naa . Ile ise itan ile yoruba ko pare ,yoo ma lo soke si ni lase eledumare. Olorun ko ni fi iku ojiji pa yin lase eledumare. Emi yin yoo gun ,E ko ni saisan lase eledumare
@OlajideAjigo6 ай бұрын
Your historical analyses take into cognizance of aborigines which in my opinion is the best account. Ori yin a ma kanke.
@OlajideAjigo6 ай бұрын
Yemen is actually the aborigines of Arab and history has justified that 👍
@adebayobambe48857 ай бұрын
You are God sent. The evidence proves it all
@kehindejosephkashimawo94107 ай бұрын
Bẹ́ẹ̀ni... Èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ń sá wọ inú èdè wa.. Nigbati mo nsọ nígbà kan pé mo máa ngbe rechargeable lantern lé ná,,, ẹnikan tó ńgbọ́ mi bú sẹ̀rin nítorí bí mo ṣe lo èdè Yorùbá yẹn.. Nitoripe mi ò wípé mo ń "charge"....Lara bí èdè oyinbo ṣe ń sá wọ inú èdè wa nìyẹn..
@raimiomoh75997 ай бұрын
Sir please who born oduduwa? Person wey born for ife no dey exist?
@ShemLogan7 ай бұрын
Ekun oko Aaŕe kakaofo Gani Adamu Logun ojo o.
@oladimejimichael-w1o7 ай бұрын
Eku eto sir
@apalarababatunde74917 ай бұрын
Sir, the igodomigodo is from the lineage of oranfe not obatala sir. And olowo arere is not a son to oduduwa but orunmila. Sir you are missing the generation together sir. Please do the corrections God bless
@iretiebiesuwa90717 ай бұрын
E ku ise takuntakun
@raimiomoh75997 ай бұрын
Una for just tell us say na Ile ife na world started from 😅😅
@crownedking25677 ай бұрын
Aare, please Ondo,Ugbo,Ekiti,Ilaje 1:13:00 do not have a similar language with Beni, nothing similar to our language with the Bini,I live and I have friends with some Binis and we cannot slightly hear or understand each other except Pele which they always say to greet us the Yoruba who they meet and they say it to themselves too
@apalarababatunde74917 ай бұрын
Sir. Oduduwa ateworan is really. The Oduduwa olofin is different from Oduduwa atewonran sir. Point of correction. The same way we have sango two versions, obatala two versions and obalufon as well please 🙏 do much of research sir. Oduduwa ateworan is of ufe odaye , Oduduwa olofin is of ufe akanlubebe. Please sir correct your narrative in that aspects . There is two versions of Oduduwa sir.