CHIEF DR LAJI ABASY, Almighty choosing you to told teach us , Our Really history of our NATION YORUBA LAND, thanks sir GOD. Send you to teach us Our Really Heritage.
@hamzatjamiu49263 жыл бұрын
Olùkọ́ àgbà may you live long
@wosilatamosu90174 жыл бұрын
Oluwa mi kuu suru pelu awa Yoruba odo Eniti olowusapamosi Ibi dada nitori ki won Ronu pada Sugbon EPE NLA TII AHOLE SE kojeki Awon tiwon gbe Ogun wa rorii rara EMI mo pe Oba mi oke abawa se ASE 🙏🙏 bn Ramadan Laji Abbas masalam
@directiondaudaalapo50264 жыл бұрын
Oro awon baba wa mio le da won lejo nitori wipe asiko yan esin pupo .won ko ni esin kan pato oro olorun koye pupo won nitori Ogun abele ni won fi para won IJa KO tan lasiko won nitori Obere lati ipilese jagunjagun apaniyan ni won se ijoba wa Tio baja tio paniyan to Jeri ilu kan wa di oluwa won wako eru wadi olowo nitori biwonse nlo ile aye won titi ti Jesu fi de tofi lo anobi gan ja Ogun titi tofi lo Ogun ko tan se afe so wipe elese.niwon ni beko bi constitution igba yan se wani sungbon Dada kokan tiwon se sile la firanti won? Imoran temi ni wipe ki lori alaafin Oyo kio bawa ro epee alaafin aole babanla re toti Ku si Oyo igboho lagbara olorun yio ri solution si nitori o mo oriki awon baba re ki abo ninu epee
@theophilusalao20308 ай бұрын
Dr. Laji Abass, mo gbadun awon series "Lehin Iku Aare Afonja!"
@crownedking25674 жыл бұрын
Gbogbo awa Yoruba gbodo fara se kan,awon ikan tosele si Baba Awolowo latowo awon Oloye Akinloye , Oloye Akinjide ati Oloye Abiola ko gbodo sele mo laarin awa Omo Oduduwa,agbajowo lafin soya.
@yusufsaheedadewale77514 жыл бұрын
Eku ise iwadi ijinle oluko agba olorun a ran oluranwo siyin
@emmanuelayelege27144 жыл бұрын
E se n ooo
@LekanMakanju4 жыл бұрын
No wonder that Obasanjo destroyed Yorubaland with all his policies as president of Nigeria and through is strategic alliances with the north.
@theophilusalao20308 ай бұрын
Obj is a foremost enemy of the Yoruba race. He doesn't even hide his disgust and hatred for anything Yoruba.
@LekanMakanju8 ай бұрын
No doubt and that's why he's unhappy that after his death, he would be forgotten
@kehindejosephkashimawo94103 жыл бұрын
Lawyer kan ti wa pẹ̀lú Oloye Gani Fawẹ̀hinmi ri tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Tẹ́wọ́ Lámúye.. Lara àwọn ònkọ̀we (editors) Nigerian Law Publications ti Gani Fawẹ̀hinmi ni (Nigerian Weekly Law Reports - NWLR). O ti farahan ni High Court Abeokuta ri, nígbàtí emì náà sì ńṣiṣẹ́ Agbẹjọ́rò fún Ìjọba (State Counsel).